Ezekiel 24:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lásán ni mò ń ṣe wahala, gbogbo ìpẹtà náà kò ní jóná.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On ti fi eke dá ara rẹ̀ lagara, ifõfo nla rẹ̀ kò si jade kuro lara rẹ̀ ifõfo rẹ̀ yio wà ninu iná.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ti fi èké dá ara rẹ̀ lágara: èrúrú rẹ̀ kò sì jáde kúrò lára rẹ̀, èrúrú náà gan an yóò wà nínú iná.