Ezekiel 24:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Pa òwe yìí fún àwọn ọlọ̀tẹ̀ wọnyi kí o sì wí fún wọn pé, ní orúkọ èmi OLUWA Ọlọrun: Gbé ìkòkò kaná; bu omi sí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Si pa owe si ọlọtẹ ilẹ na, si wi fun wọn pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi: Gbe ìkoko ka iná, gbe e kà a, si dà omi sinu rẹ̀ pẹlu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sì pa òwe yìí fún ilé ọlọ́tẹ̀ náà, sọ fún wọn pé: ‘Èyí yìí ni OLÚWA Ọlọ́run wí: “ ‘Gbé ìkòkò ìdáná náà ka iná: Gbé e kaná kí o sì da omi sí i nínú.