Ezekiel 24:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kó ègé ẹran sí i, gbogbo ibi tí ó dára jùlọ lára ẹran, ẹran itan ati ti èjìká, kó egungun tí ó dára náà sí i kí ó kún.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kó aján na jọ sinu rẹ̀, olukuluku aján ti o tobi, itan, ati apá, fi egungun ti o jọju kún inu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kó àwọn ègé ẹran tí a gé náà sínú rẹ̀, gbogbo àwọn ègé ẹran tí ó tóbi, itan àti apá. Kó àwọn egungun tí ó dára jù sínú rẹ̀