Ezekiel 25:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA Ọlọrun ní, “Nítorí àwọn ará Edomu gbẹ̀san lára àwọn ará Juda, wọ́n sì ṣẹ̀ nítorí ẹ̀san tí wọ́n gbà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Nitoripe Edomu ti huwà si ile Juda nipa gbigba ẹsan, o si ti ṣẹ̀ gidigidi, o si gbẹ̀san ara rẹ̀ lara wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Báyìí ni OLÚWA Ọlọ́run wí pé: ‘Nítorí pé Édómù gbẹ̀san lára ilé Júdà, ó sì jẹ̀bi gidigidi nípa síse bẹ́ ẹ̀,