Ezekiel 25:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo nawọ́ ìyà sí Edomu, n óo pa ati eniyan ati ẹranko inú rẹ̀ run. N óo sọ ọ́ di ahoro láti Temani títí dé Dedani. Ogun ni yóo pa wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina, bayi li Oluwa Ọlọrun wi; emi pẹlu yio nawọ mi si Edomu, emi o si ke enia ati ẹranko kuro ninu rẹ̀; emi o si sọ ọ di ahoro lati Temani; ati awọn ti Dedani, yio ti ipa idà ṣubu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nítorí náà báyìí ní OLÚWA Olódùmarè wí pé: Èmi yóò na ọwọ́ mi sórí Édómù èmi yóò sì pa àwọn ènìyàn àti àwọn ẹranko rẹ̀. Èmi yóò fi sófo láti Temanì dé Dédánì yóò ti ipa idà ṣsubú.