Ezekiel 25:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí náà, n óo nawọ́ ìyà sí wọn, n óo pa àwọn ọmọ Kereti run, n óo pa àwọn tí ó kù sí etí òkun rẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina, bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Kiyesi i, emi o nà ọwọ́ mi le awọn ara Filistia, emi o si ke awọn ara Keriti kuro, emi o si run awọn iyokù ti eti okun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nítorí náà báyìí ní OLÚWA Ọlọ́run wí pé: Èmi ti ṣetán láti na ọwọ́ mi jáde sí àwọn ará Fílísítíà Èmi yóò sì ké àwọn ará Kérétì kúrò, Èmi yóò sì pa àwọn tí ó kù ní etí kún run.