Ezekiel 26:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn erékùṣù yóo wárìrì ní ọjọ́ ìṣubú rẹ. Nítòótọ́, àwọn erékùṣù tí wọ́n wà ninu òkun yóo dààmú nítorí ìparun rẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nisisiyi ni awọn erekùṣu yio warìri li ọjọ iṣubu rẹ; nitõtọ, awọn erekùṣu ti o wà ninu okun li a o yọ lẹnu nigba atilọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nisin yìí erékùṣù wárìrì ní ọjọ́ ìṣubú rẹ; erékùṣù tí ó wà nínú òkun ni ẹ̀rù bà torí ìṣubú rẹ.’