Ezekiel 27:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Àwọn ará Pasia ati àwọn ará Ludi ati àwọn ará Puti wà láàrin àwọn ọmọ ogun rẹ bí akọni. Wọ́n gbé asà ati àṣíborí wọn kọ́ sinu rẹ, wọ́n jẹ́ kí o gba ògo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti Persia, ati ti Ludi, ati ti Futi, wà ninu ogun rẹ, awọn ologun rẹ: nwọn fi apata ati ìbori-ogun kọ́ ninu rẹ; nwọn fi ẹwà rẹ hàn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Àwọn ènìyàn Páṣíà, Lídíà àti Pútì wà nínú jagunjagun rẹ àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ogun rẹ. Wọ́n gbé àpáta àti àsíborí wọn ró sára ògiri rẹ, wọn fi ẹwà rẹ hàn.