Ezekiel 27:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Damasku bá ọ ṣòwò nítorí ọpọlọpọ ọjà ati àwọn nǹkan olówó iyebíye tí ò ń tà, wọ́n mú ọtí waini ati irun aguntan funfun wá láti Heliboni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Damasku li oniṣòwo rẹ nitori ọ̀pọlọpọ ohun ọjà ti o ṣe, nitori ọ̀pọlọpọ ọrọ̀; ni ọti-waini ti Helboni, ati irun agutan funfun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Dámásíkù, ni oníṣòwò rẹ, nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ọjà tí ó ṣe àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọrọ̀; ní ti ọtí wáìnì tí Helíbónì, àti irun àgùntàn funfun.