Ezekiel 27:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Fedani ati Jafani láti Usali a máa wá fi ọtí waini pààrọ̀ ohun tí ò ń tà; wọn a kó àwọn nǹkan èlò irin wá, ati igi kasia.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dani pẹlu ati Jafani lati Usali ngbé ọjà rẹ: irin didán, kassia, ati kalamu wà li ọjà rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Àwọn ará Dánì àti Gíríkì láti Úsálì ra ọjà títà rẹ; irin dídán, káṣíà ati kálámù ni àwọn ohun pàsípààrọ̀ ní ọjà rẹ.