Ezekiel 27:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn oníṣòwò Ṣeba ati ti Raama náà a máa bá ọ ra ọjà, oríṣìíríṣìí turari olóòórùn dídùn ati òkúta olówó iyebíye ati wúrà ni wọ́n fi ń ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́wọ́ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn oniṣòwo Ṣeba ati Rama, awọn li awọn oniṣòwo rẹ: nwọn tà onirũru turari daradara li ọjà rẹ, ati pẹlu onirũru okuta oniyebiye, ati wura.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Àwọn oníṣòwò ti Ṣébà àti Rámà, àwọn ni oníṣòwò rẹ; wọ́n ta onírúurú tùràrí olóòórùn dídùn dáradára ní ọjà rẹ, àti àwọn òkúta iyebíye àti wúrà.