Ezekiel 27:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo èbúté yóo mì tìtì nígbà tí àwọn tí wọn ń tọ́ ọkọ̀ rẹ bá kígbe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ilẹ àgbègbe yio mì nitori iró igbe awọn atọkọ̀ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ etí òkun yóò mì nítorí ìró igbe àwọn atọ́kọ̀ rẹ.