Ezekiel 27:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn atukọ̀ ni yóo jáde kúrò ninu ọkọ̀. Àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ninu ọkọ̀ ati àwọn tí ń darí ọkọ̀ yóo dúró ní èbúté.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn alajẹ̀, awọn atukọ̀, ati awọn atọ́kọ̀ okun yio sọkalẹ kuro ninu ọkọ̀ wọn, nwọn o duro lori ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn alájẹ̀ àwọn atukọ̀ àti àwọn atọ́kọ̀ ojú òkun; yóò sọ̀ kálẹ̀ kúrò nínú ọkọ̀ wọn, wọn yóò dúró lórí ilẹ̀.