Ezekiel 27:33 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn ọjà rẹ bá dé láti òkè òkun, ò ń tẹ́ ọpọlọpọ eniyan lọ́rùn. Ò ń fi ọpọlọpọ ọrọ̀ rẹ ati ọjà rẹ sọ àwọn ọba ayé di ọlọ́rọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati ọjà-tità rẹ ti okun jade wá, iwọ tẹ́ orilẹ-ède pupọ lọrun; iwọ fi ọ̀pọlọpọ ọrọ̀ rẹ, ati ọjà rẹ, sọ awọn ọba aiye di ọlọrọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ọjà títà rẹ ti òkun jáde wá ìwọ tẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ èdè lọ́rùn ìwọ fi ọrọ̀ tí ó pọ̀ àti àwọn ọjà títà rẹ sọ àwọn ọba ayé di ọlọ́rọ̀.