Ezekiel 27:34 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wàyí ò, omi òkun ti fọ́ ọ sí wẹ́wẹ́, o ti rì sí ìsàlẹ̀ òkun.’ Gbogbo àwọn ọjà rẹ ati àwọn tí ń wa ọkọ̀ rẹ ti rì pẹlu rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nisisiyi ti okun fọ́ ọ bajẹ̀ ninu ibú omi, nitorina òwo rẹ, ati gbogbo ẹgbẹ́ rẹ li ãrin rẹ, li o ṣubu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìsinsìn yìí tí òkun fọ ọ túútúú nínú ibú omi; nítorí náà òwò rẹ àti gbogbo ẹgbẹ́ rẹ ní àárin rẹ, ni yóò ṣubú.