Ezekiel 27:35 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ẹnu ya gbogbo àwọn tí ń gbé etí òkun nítorí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí ọ. Àwọn ọba wọn ń gbọ̀n jìnnìjìnnì, ẹ̀rù sì hàn ní ojú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnu yio yà gbogbo awọn olugbe erekuṣu wọnni si ọ, awọn ọba wọn yio si dijì, iyọnu yio yọ li oju wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹnu yóò ya gbogbo àwọn ti ń gbé ní erékùṣù náà sí ọ àwọn ọba wọn yóò sì dìjì, ìyọnu yóò sì yọ ní ojú wọn.