Ezekiel 27:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Igi firi láti Seniri ni wọ́n fi ṣe gbogbo ẹ̀gbẹ́ rẹ. Igi kedari láti Lẹbanoni ni wọ́n sì fi ṣe òpó ọkọ̀ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti fi apako firi ti Seniri kàn gbogbo ọkọ̀ rẹ, nwọn ti mu kedari ti Lebanoni wá lati fi ṣe opó ọkọ̀ fun ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ti fi pákó firi ti Sénárì kan gbogbo ọkọ̀ rẹ, wọ́n ti mú kédárì ti Lébánónì wá láti fi ṣe òpó ọkọ̀ fún ọ.