Ezekiel 27:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Igi oaku láti Baṣani ni wọ́n fi ṣe ajẹ̀ rẹ̀ Igi sipirẹsi láti erékùṣù Kipru ni wọ́n fi ṣe ilé rẹ. Wọ́n sì fi eyín erin bo inú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu igi oaku ti Baṣani ni nwọn ti fi gbẹ́ àjẹ rẹ; ijoko rẹ ni nwọn fi ehin-erin ṣe pelu igi boksi lati erekuṣu Kittimu wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú igi Oákù ti Báṣánì ní wọn ti fi gbẹ́ ìtukọ̀ òbèlè rẹ̀; ìjókòó rẹ ni wọn fi eyín erin ṣe pẹ̀lú igi bókísì láti erékùsù Kítímù wá