Ezekiel 27:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Sidoni ati Arifadi ni atukọ̀ rẹ. Àwọn ọlọ́gbọ́n láti ilẹ̀ Ṣemeri wà lọ́dọ̀ rẹ, àwọn ni wọ́n ń darí ọkọ̀ ojú omi rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ara ilu Sidoni ati Arfadi ni awọn ara ọkọ̀ rẹ̀: awọn ọlọgbọn rẹ, Iwọ Tire, ti o wà ninu rẹ, li awọn atọkọ̀ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ará ìlú Sídónì àti Árífádì ni àwọn ìtukọ̀ rẹ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n ẹ̀rọ rẹ, ìwọ Tírè, tí wọ́n wà nínú rẹ ni àwọn àtukọ̀ rẹ.