Ezekiel 29:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n gba yín mú, dídá ni ẹ dá mọ́ wọn lọ́wọ́, tí ẹ ya wọ́n léjìká pẹ́rẹpẹ̀rẹ. Nígbà tí wọ́n gbára le yín, ẹ dá ẹ sì jẹ́ kí wọ́n dá lẹ́yìn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn di ọ lọwọ mu, iwọ fọ́, o si ya gbogbo èjiká wọn: nigbati nwọn si fi ara tì ọ, iwọ ṣẹ́, o si mu gbogbo ẹgbẹ́ wọn gbọ̀n.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí wọn fi ọwọ́ agbára wọn dì ọ́ mú. Ìwọ fọ́, ìwọ sì ya gbogbo èjìká wọn; nígbà tí wọn fi ara tì ọ́, ìwọ sẹ́, ìwọ sì mú gbogbo ẹ̀gbẹ́ wọn gbọ̀n.