Ezekiel 29:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ilẹ̀ Ijipti yóo di ahoro, yóo sì di aṣálẹ̀. Wọn yóo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA. “Nítorí o wí pé, ‘Èmi ni mo ni odò Naili, ara mi ni mo dá a fún,’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ Egipti yio si di aginjù yio si di ahoro; nwọn o si mọ̀ pe emi li Oluwa: nitori ti o ti wipe, Odò na temi ni, emi li o si ti wà a.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ Éjíbítì yóò di ihà àti ahoro, nígbà náà ní wọn yóò sì mọ̀ wí pé èmi ní OLÚWA. “ ‘Nítorí tí ìwọ wí pé, “Tèmi ni odò Náílì; Èmi ni mo ṣe é,”