Ezekiel 3:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lọ bá àwọn eniyan rẹ tí wọ́n wà ní ìgbèkùn, kí o sọ ohun tí OLUWA Ọlọrun sọ fún wọn; wọn ìbáà gbọ́, wọn ìbáà má sì gbọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Si lọ, tọ̀ awọn ti igbekùn lọ, awọn ọmọ enia rẹ, si ba wọn sọ̀rọ, ki o si wi fun wọn pe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; bi nwọn o gbọ́, tabi bi nwọn o kọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lọ nísinsìnyìí sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn rẹ tó wà ní ìgbèkùn. Sọ fún wọn pé báyìí ni OLÚWA Ọlọ́run wí yálà wọ́n gbọ́ tàbí wọn kò gbọ́.”