Ezekiel 3:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni ẹ̀mí gbé mi dìde, mo sì gbọ́ ìró kan lẹ́yìn mi tí ó dàbí ariwo ìṣẹ̀lẹ̀ ńlá, ó ní, “Ẹ fi ìyìn fún ìfarahàn ògo OLUWA ní ibùgbé rẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹmi si gbe mi soke, mo si gbọ́ ohùn iró nla lẹhin mi, nwipe, Ibukun ni fun ogo Oluwa lati ipò rẹ̀ wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Ẹ̀mí gbé mi sókè, mo sì gbọ́ ohùn ìró ńlá lẹ́yìn mi-tó sọ pé, kí a gbé ògo OLÚWA ga láti ibùgbé rẹ̀ wá!