Ezekiel 3:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kì í sá ṣe àwọn tí wọn ń sọ èdè mìíràn tí ó ṣòro gbọ́, ni mo rán ọ sí, àwọn ọmọ ilé Israẹli ni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori a kò ran ọ si enia ède ajeji ati sisọrọ, ṣugbọn si ile Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A kò rán ọ sí àwọn tó ń sọ èdè àjèjì tàbí tí èdè wọn ṣòro láti gbọ́, ṣùgbọ́n orílẹ̀ èdè Ísírẹ́lì ni mo rán ọ sí