Ezekiel 3:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo ti mú kí ojú rẹ le sí tiwọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, mo ti sọ oju rẹ di lile si oju wọn, ati iwaju rẹ di lile si iwaju wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n bí i ti wọn lèmi náà yóò ṣe jẹ́ kí ojú àti ọkàn rẹ le.