Ezekiel 30:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Òun ati àwọn eniyan rẹ̀, tí wọ́n jẹ́ orílẹ̀-èdè oníjàgídíjàgan jùlọ ni, yóo wá pa ilẹ̀ Ijipti run, wọn yóo yọ idà ti Ijipti, ọpọlọpọ yóo sì kú ní ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On ati enia rẹ̀ pẹlu rẹ̀, ẹ̀ru awọn orilẹ-ède, li a o mu wá pa ilẹ na run: nwọn o si fà idà wọn yọ si Egipti, nwọn o si fi awọn ti a pa kún ilẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun àti àwọn ológun rẹ̀ ẹ́rù àwọn orílẹ̀-èdè ní a o mú wá láti pa ilẹ náà run. Wọn yóò fa idà wọn yọ sí Éjíbítì ilẹ̀ náà yóò sì kún fún àwọn tí a pa.