Ezekiel 30:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe ṣe ìdájọ́ Ijipti, wọn óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li emi o mu idajọ ṣẹ ni Egipti: nwọn o si mọ̀ pe emi li Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà Èmi yóò mú ki ìjìyà wá sórí Éjíbítì, wọn yóò sì mọ̀ pé Èmi ni OLÚWA.’ ”