Ezekiel 30:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo fọ́n àwọn ará Ijipti ká sáàrin àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, n óo sì tú wọn káàkiri gbogbo ilẹ̀ ayé. Wọn óo sì mọ̀ pé èmi ni OLUWA.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o si tú awọn ara Egipti ká sãrin awọn orilẹ-ède, emi o si tú wọn ká sãrin awọn ilẹ; nwọn o si mọ̀ pe emi li Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò fọ́n àwọn ara Éjíbítì ká sí àárin orílẹ̀ èdè, èmi yóò sì tú wọn ká sí àárin orílẹ̀ èdè, èmi yóò sì tú wọn ká sí gbogbo ilẹ̀. Nígbà náà wọn yóò mọ̀ pé èmi ni OLÚWA.”