Ezekiel 30:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
‘Ẹ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn nítorí ọjọ́ burúkú tí ń bọ̀, nítorí ọjọ́ náà súnmọ́lé, ọjọ́ OLUWA ti dé tán, yóo jẹ́ ọjọ́ ìṣúdudu ati ìparun fún àwọn orílẹ̀-èdè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ọjọ na sunmọ tosí, ani ọjọ Oluwa sunmọ tosi, ọjọ ikũkũ ni; yio jẹ akoko ti awọn keferi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ọjọ́ náà sún mọ́ tòsí àní ọjọ́ OLÚWA sún mọ́ tòsí Ọjọ́ tí ọjọ́ ìkùukùu ṣú dúdú, àsìkò ìparun fún àwọn aláìkọlà