Ezekiel 30:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn yóo mọ̀ pé èmi ni OLUWA nígbà tí mo bá dáná sun Ijipti, tí gbogbo àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ bá ṣubú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o si mọ̀ pe emi li Oluwa, nigbati mo bá gbe iná kalẹ ni Egipti, ti gbogbo awọn olùranlọ́wọ rẹ̀ bá parun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn náà wọn yóò mọ̀ pé èmi ní OLÚWA, nígbà tí mo bá gbé iná kalẹ̀ ní Ijíbítì tí gbogbo àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ bá parun.