Ezekiel 31:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wò ó! Mo fi ọ́ wé igi kedari Lẹbanoni, àwọn ẹ̀ka rẹ̀ lẹ́wà, wọ́n sì ní ìbòòji ó ga fíofío, orí rẹ̀ sì kan ìkùukùu lójú ọ̀run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, awọn ara Assiria ni igi kedari ni Lebanoni ti o li ẹ̀ka daradara, ti o si ṣiji boni, ti o si ga, ṣonṣo ori rẹ̀ si wà lãrin awọn ẹ̀ka bibò.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyèsí Ásíríà, tí ó jẹ́ òpépé igi ni Lébánónì ní ìgbà kan rí, pẹ̀lú àwọn ẹ̀ka dáradára tí ó ṣe ìji bo igbó náà; tí ó ga sókè, òkè rẹ̀ lókè ni ewé tí ó nípọn wà.