Ezekiel 31:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó tóbi, ó lọ́lá ẹ̀ka rẹ̀ sì lẹ́wà nítorí pé gbòǹgbò rẹ̀ wọ ilẹ̀ lọ, ó sì kan ọpọlọpọ omi nísàlẹ̀ ilẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li o ni ẹwà ninu titobi rẹ̀, ninu gigùn ẹ̀ka rẹ̀: nitori ti egbò rẹ̀ wà li ẹbá omi nla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlá ńlá ní ẹwà rẹ̀ jẹ́, pẹ̀lú títẹ́ rẹrẹ ẹ̀ka rẹ̀, nítorí gbòǹgbò rẹ̀ lọ sí ìsàlẹ̀ sí ibi tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi wà.