Ezekiel 31:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo dá a ní arẹwà, pẹlu ẹ̀ka tí ó pọ̀. Gbogbo igi ọgbà Edẹni, tí ó wà ninu ọgbà Ọlọrun sì ń jowú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi ti ṣe e ni ẹwà nipa ọ̀pọlọpọ ẹ̀ka rẹ̀: tobẹ̃ ti gbogbo igi Edeni, ti o wà ninu ọgbà Ọlọrun, ṣe ilara rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo mú kí ó ní ẹwà pẹ̀lú ẹ̀ka lọ́pọ̀lọpọ̀ tó fi jẹ́ ìlara àwọn igi gbogbo ní Édẹ́nì tí í ṣe ọgbà Ọlọ́run.