Ezekiel 32:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA Ọlọrun sọ fún ọba Ijipti pé, “Ọba Babiloni yóo fi idà pa yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Idà ọba Babiloni yio wá sori rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Nítorí èyí yìí ní OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí: “ ‘Idà Ọba Bábílónì yóò wá sí orí rẹ,