Ezekiel 33:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo sọ ilẹ̀ yìí di ahoro ati aṣálẹ̀. Agbára tí ó ń gbéraga sí yóo dópin. Àwọn òkè Israẹli yóo di ahoro tóbẹ́ẹ̀ tí ẹnikẹ́ni kò ní gba ibẹ̀ kọjá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti emi o sọ ilẹ na di ahoro patapata, ọ̀ṣọ nla agbara rẹ̀ kì yio si mọ, awọn oke Israeli yio si di ahoro, ti ẹnikan kì yio le là a kọja.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò mú kí ilẹ náà di ahoro, agbára ìgbéraga rẹ̀ yóò sì di ahoro kí ẹnikẹ́ni má ṣe ré wọn kọjá.