Ezekiel 33:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
bí ó bá rí ogun tí ń bọ̀ wá sí ilẹ̀ náà, tí ó bá fọn fèrè tí ó fi kìlọ̀ fún àwọn eniyan,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi on bá ri ti idà mbọ̀ wá sori ilẹ na ti o bá fun ipè, ti o si kìlọ fun awọn enia na:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
tí ó sì rí i pé idà ń bọ̀ lórí ilẹ̀ náà, tí ó sì fọn ìpè láti kìlọ̀ fún àwọn ènìyàn,