Ezekiel 33:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
bí ẹnìkan bá gbọ́ ìró fèrè náà, ṣugbọn tí kò bá bìkítà fún ogun àgbọ́-tẹ́lẹ̀ yìí, bí ogun bá pa á orí ara rẹ̀ ni ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ yóo wà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ẹnikẹni ti o bá gbọ́ iró ipè, ti kò si gbà ìkilọ; bi idà ba de, ti o si mu on kuro, ẹjẹ rẹ̀ yio wà lori on tikalarẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nígbà náà tí ẹnikẹ́ni bá gbọ́ ìpè ṣùgbọ́n tí kò gbọ́ ìkìlọ̀, tí idà náà wá tí ó sì gba ẹ̀mí rẹ̀, ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ yóò wà lórí ara rẹ̀.