Ezekiel 34:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn óo mọ̀ pé èmi, OLUWA Ọlọrun wọn, wà pẹlu wọn, ati pé àwọn ọmọ Israẹli sì ni eniyan mi. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi ni nwọn o mọ̀ pe emi Oluwa Ọlọrun wọn wà pẹlu wọn, ati awọn, ile Israeli, jẹ enia mi, li Oluwa Ọlọrun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé, èmi ni OLÚWA Ọlọ́run wọn, èmi wà pẹ̀lú wọn àti pé, àwọn ilé Ísírẹ́lì jẹ́ ènìyàn mi, ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí.