Ezekiel 35:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ óo mọ̀ pé èmi OLUWA gbọ́ gbogbo ohun tí ẹ̀ ń sọ sí àwọn òkè Israẹli, pé wọ́n ti di ahoro ati ìkógun fun yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o si mọ̀ pe emi li Oluwa, ati pe emi ti gbọ́ ọ̀rọ buburu rẹ, ti iwọ ti sọ si oke Israeli, wipe, A sọ wọn di ahoro, a fi wọn fun wa lati run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ̀ pé èmi OLÚWA ti gbọ gbogbo ohun ẹ̀gàn tí ìwọ ti sọ lòdì sí àwọn òkè Ísírẹ́lì náà. Ìwọ wí pé, “A ti fi wọ́n sílẹ̀ ní ṣíṣọ̀fọ̀, a sì fi fún wa láti pajẹ.”