Ezekiel 35:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo sọ àwọn ìlú rẹ di aṣálẹ̀ ìwọ pàápàá yóo sì di ahoro; o óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o sọ awọn ilu rẹ di ahoro, iwọ o si di ahoro, iwọ o si mọ̀ pe, emi li Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmì yóò pa àwọn ìlú rẹ run, ìwọ yóò sì di ahoro. Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ̀ pé èmi ni OLÚWA.