Ezekiel 35:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo sọ òkè Seiri di aṣálẹ̀ ati ahoro. N óo pa gbogbo àwọn tí ń lọ tí ń bọ̀ níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li emi o sọ oke Seiri di ahoro patapata, emi o si ké ẹniti nkọja lọ ati ẹniti npadà bọ̀ kuro ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò mú kí òkè Séírì di ahoro; ọ̀fọ̀ gbogbo àwọn tí ó ńlọ tí ó ń bọ̀ ní èmi yóò gé kúrò lára rẹ.