Ezekiel 36:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọ̀tá ń yọ̀ yín, wọ́n ń sọ pé, àwọn òkè àtijọ́ ti di ogún àwọn.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa Ọlọrun wi, Nitori ti ọta ti wi si nyin pe, Aha, ani ibi giga igbãni jẹ tiwa ni ini:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí yìí ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí: Àwọn ọ̀tá sọ nípa yín pé, “Áà! Àwọn ibi gíga ìgbàanì ti di ohun ìní wa.” ’