Ezekiel 37:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Agbára OLUWA sọ̀kalẹ̀ sára mi, ẹ̀mí rẹ̀ sì gbé mi wá sinu àfonífojì tí ó kún fún egungun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ỌWỌ́ Oluwa wà li ara mi, o si mu mi jade ninu ẹmi Oluwa, o si gbe mi kalẹ li ãrin afonifojì ti o kún fun egungun,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọwọ́ OLÚWA wà lára mi, ó sì mú mi jáde pẹ̀lú ẹ̀mí OLÚWA, ó mú kí ń wà ní àárin àfonífojì; ti o kún fún àwọn egungun.