Ezekiel 38:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ṣugbọn ní ọjọ́ tí Gogu bá gbógun ti ilẹ̀ Israẹli, inú mi óo ru. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si ṣe nigbakanna li ákoko ti Gogu yio wá dojukọ ilẹ Israeli, ni Oluwa Ọlọrun wi, ti irúnu mi yio yọ li oju mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ náà: Nígbà tí Gógì bá kọlu ilẹ̀ Ísírẹ́lì, gbígbóná ibínú mi yóò ru sókè, ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí.