Ezekiel 38:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Pẹlu ìtara ati ìrúnú ni mo fi ń sọ pé ilẹ̀ Israẹli yóo mì tìtì ní ọjọ́ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ni ijowu mi ati ni iná ibinu mi ni mo ti sọ̀rọ, Nitõtọ li ọjọ na mimì nla kan yio wà ni ilẹ Israeli;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìtara mi àti ní gbígbóná ìbínú mi, Mo tẹnumọ́-ọn pé; ní àsìkò náà ilẹ̀ mímì tíi ó lágbára ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì yóò ṣẹlẹ̀.