Ezekiel 38:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Pasia, ati àwọn ará Kuṣi, ati àwọn ará Puti wà pẹlu rẹ̀; gbogbo wọn, tàwọn ti apata ati àṣíborí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Persia, Etiopia, ati Libia pẹlu wọn; gbogbo wọn pẹlu asà on akoro:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Páṣíà, Kúsì àti Pútì yóò wà pẹ̀lú wọn, gbogbo wọn yóò wà pẹ̀lú asà àti ìsíborí wọn