Ezekiel 38:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dira ogun, kí o sì wà ní ìmúrasílẹ̀, ìwọ ati gbogbo eniyan tí wọ́n pé yí ọ ká, kí o jẹ́ olórí ẹ̀ṣọ́ fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ mura silẹ, si mura fun ara rẹ, iwọ, ati gbogbo ẹgbẹ́ rẹ ti a gbajọ fun ọ, ki iwọ jẹ alãbo fun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Múra sílẹ̀, múra tán, kí ìwọ àti gbogbo ìjọ náà péjọpọ̀ pẹ̀lú rẹ, kí o sì pàṣẹ fún wọn.