Ezekiel 39:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo tú ẹ̀mí mi lé àwọn ọmọ Israẹli lórí, n ko ní gbé ojú mi kúrò lọ́dọ̀ wọn mọ́. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi kì yio si fi oju mi pamọ kuro lọdọ wọn mọ: nitori emi ti tú ẹmi mi sori ile Israeli, ni Oluwa Ọlọrun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi kì yóò sì fi ojú mi pamọ́ kúrò lọ́dọ̀ wọn mọ nítorí èmi yóò tú èémí mi jáde sí ilé Ísírẹ́lì, ní OLÚWA Ọba wí.”