Ezekiel 4:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA bá wí fún mi pé, “Kò burú, n óo jẹ́ kí o fi ìgbẹ́ mààlúù dáná láti fi dín àkàrà rẹ, dípò ìgbẹ́ eniyan.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni o wi fun mi pe, Wõ, mo ti fi ẹlẹbọtọ fun ọ dipò igbẹ́ enia, iwọ o si fi ṣe akara rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ló wí fún mi pé, “Wò ó, Èmi ó fún ọ ní ìgbẹ́ màlúù dípò ìgbẹ́ ènìyàn. Èmi yóò mú ki ó dín àkàrà rẹ lórí ìgbẹ́ màlúù dípò igbẹ ènìyàn.”