Ezekiel 4:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo ṣe bẹ́ẹ̀ kí wọ́n lè ṣe aláìní oúnjẹ ati omi, kí wọ́n lè máa wo ara wọn pẹlu ìpayà, kí wọ́n sì parun nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki nwọn ki o le ṣe alaini akara ati omi, ki olukuluku wọn ki o le yanu si ọmọ-nikeji rẹ̀, ki nwọn si run nitori ẹ̀ṣẹ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nítorí pé oúnjẹ àti omi yóò wọ́n. Wọn yóò máa wo ara wọn pẹ̀lú ìyanu, èmi yóò sì jẹ́ kí wọ́n ṣọ̀fọ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.